-
1 Àwọn Ọba 21:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Dìde, lọ pàdé Áhábù ọba Ísírẹ́lì tó wà ní Samáríà.+ Ó wà nínú ọgbà àjàrà Nábótì, níbi tí ó ti lọ gbà á. 19 Kí o sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “O ti pa ọkùnrin yìí+ o sì ti sọ nǹkan ìní rẹ̀ di tìrẹ,* àbí?”’+ Kí o wá sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ibi tí àwọn ajá ti lá ẹ̀jẹ̀ Nábótì, ni àwọn ajá ti máa lá ẹ̀jẹ̀ rẹ.”’”+
-