Émọ́sì 3:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa yín, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, nípa gbogbo ìdílé tí mo mú jáde kúrò nílẹ̀ Íjíbítì: 2 ‘Ẹ̀yin nìkan ni mo mọ̀ nínú gbogbo ìdílé tó wà láyé.+ Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ẹ jíhìn nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín.+
3 “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa yín, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, nípa gbogbo ìdílé tí mo mú jáde kúrò nílẹ̀ Íjíbítì: 2 ‘Ẹ̀yin nìkan ni mo mọ̀ nínú gbogbo ìdílé tó wà láyé.+ Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ẹ jíhìn nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín.+