Hósíà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+
8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+