ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,

      Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,

      Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,

      Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.

  • Àìsáyà 60:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,

      Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+

      Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,

      Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+

  • Ìdárò 3:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+

      Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+

  • Hósíà 11:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ṣé ó yẹ kí n yọwọ́ lọ́rọ̀ rẹ, ìwọ Éfúrémù?+

      Ṣé ó yẹ kí n fà ọ́ lé ọ̀tá lọ́wọ́, ìwọ Ísírẹ́lì?

      Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bí Ádímà?

      Ṣé ó yẹ kí n ṣe ọ́ bíi Sébóíímù?+

      Mo ti yí ọkàn mi pa dà;

      Lẹ́sẹ̀ kan náà, inú mi ti yọ́* sí wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́