Ọbadáyà 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ àwọn tó sá àsálà yóò wà lórí Òkè Síónì,+Yóò sì di mímọ́;+Ilé Jékọ́bù yóò sì gba àwọn nǹkan tó jẹ́ tiwọn.+
17 Àmọ́ àwọn tó sá àsálà yóò wà lórí Òkè Síónì,+Yóò sì di mímọ́;+Ilé Jékọ́bù yóò sì gba àwọn nǹkan tó jẹ́ tiwọn.+