Jóẹ́lì 2:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò sì rí ìgbàlà;+Torí àwọn tó sá àsálà yóò wà ní Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù+ bí Jèhófà ṣe sọ,Àwọn tó là á já tí Jèhófà pè.”
32 Gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò sì rí ìgbàlà;+Torí àwọn tó sá àsálà yóò wà ní Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù+ bí Jèhófà ṣe sọ,Àwọn tó là á já tí Jèhófà pè.”