2 Kíróníkà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí náà, ó lọ bá Ásà, ó sì sọ fún un pé: “Gbọ́ mi, ìwọ Ásà àti gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì! Jèhófà á máa wà pẹ̀lú yín tí ẹ ò bá ti fi í sílẹ̀;+ tí ẹ bá sì wá a, á jẹ́ kí ẹ rí òun,+ àmọ́ tí ẹ bá fi í sílẹ̀, á fi yín sílẹ̀.+ Míkà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+
2 Nítorí náà, ó lọ bá Ásà, ó sì sọ fún un pé: “Gbọ́ mi, ìwọ Ásà àti gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì! Jèhófà á máa wà pẹ̀lú yín tí ẹ ò bá ti fi í sílẹ̀;+ tí ẹ bá sì wá a, á jẹ́ kí ẹ rí òun,+ àmọ́ tí ẹ bá fi í sílẹ̀, á fi yín sílẹ̀.+
11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+