ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 5:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí pé ẹ̀ ń gba owó oko* lọ́wọ́ àwọn aláìní tí ẹ gbé oko fún

      Ẹ sì ń gba ọkà lọ́wọ́ wọn bí ìṣákọ́lẹ̀,*+

      Ẹ kò ní máa gbé inú àwọn ilé tí ẹ fi òkúta gbígbẹ́ kọ́+

      Bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní máa mu wáìnì àwọn ọgbà àjàrà dáradára tí ẹ gbìn.+

  • Émọ́sì 8:4-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ni àwọn tálákà lára

      Tí ẹ sì ń pa àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ilẹ̀ yìí,+

       5 Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ pé, ‘Ìgbà wo ni àjọ̀dún òṣùpá tuntun máa parí,+ ká lè ta àwọn hóró ọkà wa,

      Àti ìparí Sábáàtì,+ ká lè gbé hóró ọkà lọ fún títà?

      Ká lè sọ òṣùwọ̀n eéfà* di kékeré

      Kí a sì sọ ṣékélì* di ńlá,

      Kí a dọ́gbọ́n sí àwọn òṣùwọ̀n wa, kí a lè fi tanni jẹ;+

       6 Kí a lè fi fàdákà ra àwọn aláìní

      Kí a sì fi owó bàtà ẹsẹ̀ méjì ra àwọn tálákà,+

      Kí a sì lè ta èyí tí kò dáa lára ọkà.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́