Jónà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà, jọ̀ọ́ gbẹ̀mí* mi, torí ó sàn kí n kú ju kí n wà láàyè.”+