Sáàmù 106:38, 39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀. 39 Àwọn iṣẹ́ wọn sọ wọ́n di aláìmọ́,Wọ́n sì ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀. 39 Àwọn iṣẹ́ wọn sọ wọ́n di aláìmọ́,Wọ́n sì ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+