-
Àìsáyà 54:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 39:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò dá àwọn èèyàn Jékọ́bù tí wọ́n kó lẹ́rú pa dà,+ màá sì ṣàánú gbogbo ilé Ísírẹ́lì;+ èmi yóò fi ìtara gbèjà orúkọ mímọ́ mi.*+ 26 Lẹ́yìn tí wọ́n bá sì ti dójú tì wọ́n torí gbogbo ìwà àìṣòótọ́ tí wọ́n hù sí mi,+ wọn yóò máa gbé lórí ilẹ̀ wọn láìséwu, ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n.+
-