Sekaráyà 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
9 Kún fún ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì. Kígbe ìṣẹ́gun, ìwọ ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù. Wò ó! Ọba rẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ.+ Olódodo ni, ó sì ń mú ìgbàlà bọ̀,*Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀,+ ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,Àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ọmọ abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+