-
Àìsáyà 10:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Torí náà, ohun tí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ẹ̀yin èèyàn mi tó ń gbé ní Síónì, ẹ má bẹ̀rù nítorí ará Ásíríà tó ti máa ń fi ọ̀pá lù yín,+ tó sì máa ń gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè sí yín bíi ti Íjíbítì.+ 25 Torí kò ní pẹ́ rárá tí ìbáwí náà fi máa dópin; ìbínú mi máa mú kí n pa wọ́n run.+
-