Àìsáyà 52:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+ Róòmù 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Báwo ni wọ́n á sì ṣe wàásù láìjẹ́ pé a rán wọn jáde?+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹsẹ̀ àwọn tó ń kéde ìhìn rere àwọn ohun rere mà rẹwà o!”+
7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+
15 Báwo ni wọ́n á sì ṣe wàásù láìjẹ́ pé a rán wọn jáde?+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹsẹ̀ àwọn tó ń kéde ìhìn rere àwọn ohun rere mà rẹwà o!”+