Náhúmù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ọjọ́ tí Nínéfè+ ti wà ló ti dà bí adágún omi,Àmọ́ ní báyìí, wọ́n ń sá lọ. “Ẹ dúró! Ẹ dúró!” Àmọ́ kò sí ẹni tó yíjú pa dà.+
8 Láti ọjọ́ tí Nínéfè+ ti wà ló ti dà bí adágún omi,Àmọ́ ní báyìí, wọ́n ń sá lọ. “Ẹ dúró! Ẹ dúró!” Àmọ́ kò sí ẹni tó yíjú pa dà.+