1 Tímótì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín. Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+
17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín.
3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+