-
Jeremáyà 50:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ìró àwọn tó ń sá lọ ń dún,
Àwọn tó ń sá àsálà láti ilẹ̀ Bábílónì,
Láti kéde ẹ̀san Jèhófà Ọlọ́run wa ní Síónì,
Ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.+
-
-
Jeremáyà 51:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Màá san án pa dà fun Bábílónì àti fún gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kálídíà
Nítorí gbogbo búburú tí wọ́n ti ṣe ní Síónì lójú yín,”+ ni Jèhófà wí.
-