Sáàmù 68:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́run jẹ́ ẹgbẹẹgbàárùn-ún, ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún.+ Jèhófà wá láti Sínáì sínú ibi mímọ́.+
17 Àwọn kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́run jẹ́ ẹgbẹẹgbàárùn-ún, ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún.+ Jèhófà wá láti Sínáì sínú ibi mímọ́.+