ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 5:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 ‘Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fẹ́ kí ọjọ́ Jèhófà dé, ẹ gbé!+

      Àǹfààní wo wá ni ọjọ́ Jèhófà máa ṣe yín?+

      Òkùnkùn ló máa jẹ́, kì í ṣe ìmọ́lẹ̀.+

  • Émọ́sì 5:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ọjọ́ Jèhófà máa jẹ́ òkùnkùn, kì í ṣe ìmọ́lẹ̀;

      Ó máa jẹ́ ìṣúdùdù, kì í ṣe ìtànyòò.

  • Ìṣe 2:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀, kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ olókìkí Jèhófà* tó dé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́