-
Sekaráyà 6:11-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí o fi fàdákà àti wúrà ṣe adé,* kí o sì fi dé orí Àlùfáà Àgbà Jóṣúà+ ọmọ Jèhósádákì. 12 Kí o sì sọ fún un pé,
“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ 13 Òun ni yóò kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà, òun ni iyì máa tọ́ sí. Yóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀, yóò sì ṣàkóso, yóò sì tún jẹ́ àlùfáà lórí ìtẹ́ rẹ̀,+ ọ̀kan kò sì ní pa èkejì lára.*
-