1 Kíróníkà 3:17-19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn ọmọ Jekonáyà ẹlẹ́wọ̀n ni Ṣéálítíẹ́lì, 18 Málíkírámù, Pedáyà, Ṣẹ́násà, Jekamáyà, Hóṣámà àti Nedabáyà. 19 Àwọn ọmọ Pedáyà ni Serubábélì+ àti Ṣíméì; àwọn ọmọ Serubábélì sì ni Méṣúlámù àti Hananáyà (Ṣẹ́lómítì ni arábìnrin wọn); Sekaráyà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Serubábélì ló fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí,+ ọwọ́ rẹ̀ náà ni yóò sì parí rẹ̀.+ Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín.
17 Àwọn ọmọ Jekonáyà ẹlẹ́wọ̀n ni Ṣéálítíẹ́lì, 18 Málíkírámù, Pedáyà, Ṣẹ́násà, Jekamáyà, Hóṣámà àti Nedabáyà. 19 Àwọn ọmọ Pedáyà ni Serubábélì+ àti Ṣíméì; àwọn ọmọ Serubábélì sì ni Méṣúlámù àti Hananáyà (Ṣẹ́lómítì ni arábìnrin wọn);
9 “Serubábélì ló fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí,+ ọwọ́ rẹ̀ náà ni yóò sì parí rẹ̀.+ Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín.