ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní ọdún kejì, lẹ́yìn tí wọ́n wá sínú ilé Ọlọ́run tòótọ́ ní Jerúsálẹ́mù, ní oṣù kejì, Serubábélì ọmọ Ṣéálítíẹ́lì àti Jéṣúà ọmọ Jèhósádákì àti ìyókù àwọn arákùnrin wọn, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì pẹ̀lú gbogbo àwọn tó jáde wá sí Jerúsálẹ́mù láti ìgbèkùn+ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà; wọ́n yan àwọn ọmọ Léfì, láti ẹni ogún (20) ọdún sókè láti jẹ́ alábòójútó lórí iṣẹ́ ilé Jèhófà.

  • Ẹ́sírà 3:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Nígbà tí àwọn kọ́lékọ́lé fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì Jèhófà lélẹ̀,+ àwọn àlùfáà wọ aṣọ iṣẹ́ wọn, wọ́n mú kàkàkí+ dání, àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn àwọn ọmọ Ásáfù mú síńbálì* dání, wọ́n dìde dúró láti yin Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ìlànà tí Dáfídì ọba Ísírẹ́lì fi lélẹ̀.+

  • Ẹ́sírà 5:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Bákan náà, látinú tẹ́ńpìlì Bábílónì, Ọba Kírúsì kó àwọn ohun èlò wúrà àti fàdákà ilé Ọlọ́run jáde, èyí tí Nebukadinésárì kó kúrò nínú tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù lọ sí tẹ́ńpìlì Bábílónì.+ Ọba Kírúsì kó wọn fún ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Ṣẹṣibásà,*+ ẹni tí Kírúsì fi ṣe gómìnà.+

  • Ẹ́sírà 5:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Nígbà tí Ṣẹṣibásà yìí dé, ó fi ìpìlẹ̀ ilé Ọlọ́run lélẹ̀,+ èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù; àtìgbà yẹn ni wọ́n sì ti ń kọ́ ilé náà títí di báyìí, àmọ́ wọn ò tíì parí rẹ̀.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́