Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’ Sekaráyà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ̀yin ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì, bí ẹ ṣe di ẹni ègún láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ bẹ́ẹ̀ náà ni èmi yóò gbà yín là, ẹ ó sì di ẹni ìbùkún.+ Ẹ má bẹ̀rù!+ Ẹ jẹ́ onígboyà.’*+
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
13 Ẹ̀yin ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì, bí ẹ ṣe di ẹni ègún láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ bẹ́ẹ̀ náà ni èmi yóò gbà yín là, ẹ ó sì di ẹni ìbùkún.+ Ẹ má bẹ̀rù!+ Ẹ jẹ́ onígboyà.’*+