Ẹ́sírà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n fún àwọn agékùúta+ àti àwọn oníṣẹ́ ọnà+ lówó, wọ́n tún kó oúnjẹ àti ohun mímu pẹ̀lú òróró fún àwọn ọmọ Sídónì àti àwọn ará Tírè, torí wọ́n kó gẹdú igi kédárì láti Lẹ́bánónì gba orí òkun wá sí Jópà,+ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Kírúsì ọba Páṣíà fún wọn.+
7 Wọ́n fún àwọn agékùúta+ àti àwọn oníṣẹ́ ọnà+ lówó, wọ́n tún kó oúnjẹ àti ohun mímu pẹ̀lú òróró fún àwọn ọmọ Sídónì àti àwọn ará Tírè, torí wọ́n kó gẹdú igi kédárì láti Lẹ́bánónì gba orí òkun wá sí Jópà,+ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Kírúsì ọba Páṣíà fún wọn.+