28 “Bí mo ṣe kíyè sí wọn láti fà wọ́n tu, láti ya wọ́n lulẹ̀, láti fà wọ́n ya, láti pa wọ́n run àti láti ṣe wọ́n léṣe,+ bẹ́ẹ̀ ni màá kíyè sí wọn láti kọ́ wọn bí ilé àti láti gbìn wọ́n,”+ ni Jèhófà wí.
42 “Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Bí mo ti mú gbogbo àjálù ńlá yìí bá àwọn èèyàn yìí, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe mú gbogbo oore* tí mo ṣèlérí fún wọn wá sórí wọn.+