Àìsáyà 54:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+ Ìnilára máa jìnnà réré sí ọ,+O ò ní bẹ̀rù ohunkóhun, ohunkóhun ò sì ní já ọ láyà,Torí pé kò ní sún mọ́ ọ.+
14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+ Ìnilára máa jìnnà réré sí ọ,+O ò ní bẹ̀rù ohunkóhun, ohunkóhun ò sì ní já ọ láyà,Torí pé kò ní sún mọ́ ọ.+