Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’ Jóẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Sekaráyà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà yóò dáàbò bo àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù;+ ní ọjọ́ yẹn, ẹni tó bá kọsẹ̀* nínú wọn yóò dà bíi Dáfídì, ilé Dáfídì yóò sì dà bí Ọlọ́run, bí áńgẹ́lì Jèhófà tó ń lọ níwájú wọn.+
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
8 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà yóò dáàbò bo àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù;+ ní ọjọ́ yẹn, ẹni tó bá kọsẹ̀* nínú wọn yóò dà bíi Dáfídì, ilé Dáfídì yóò sì dà bí Ọlọ́run, bí áńgẹ́lì Jèhófà tó ń lọ níwájú wọn.+