Ìsíkíẹ́lì 34:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+ Míkà 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó máa dìde dúró, Jèhófà yóò sì fún un lókun láti ṣe olùṣọ́ àgùntàn,+Nípasẹ̀ orúkọ ńlá Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀. Ààbò yóò sì wà lórí wọn,+Torí àwọn èèyàn máa mọ̀ ní gbogbo ìkángun ayé pé ó tóbi lọ́ba.+ Jòhánù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà;+ olùṣọ́ àgùntàn àtàtà máa ń fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.+ Hébérù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun,
23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+
4 Ó máa dìde dúró, Jèhófà yóò sì fún un lókun láti ṣe olùṣọ́ àgùntàn,+Nípasẹ̀ orúkọ ńlá Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀. Ààbò yóò sì wà lórí wọn,+Torí àwọn èèyàn máa mọ̀ ní gbogbo ìkángun ayé pé ó tóbi lọ́ba.+
20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun,