ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hágáì 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “‘Àmọ́ ní báyìí, ìwọ Serubábélì, jẹ́ onígboyà. Kí ìwọ Jóṣúà ọmọ Jèhósádákì, àlùfáà àgbà pẹ̀lú sì jẹ́ onígboyà,’ ni Jèhófà wí.

      “‘Kí gbogbo ẹ̀yin èèyàn ilẹ̀ náà pẹ̀lú jẹ́ onígboyà,+ kí ẹ sì ṣiṣẹ́’ ni Jèhófà wí.

      “‘Torí mo wà pẹ̀lú yín,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.

  • Ìfihàn 11:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Màá mú kí àwọn ẹlẹ́rìí mi méjì fi ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà ọjọ́ (1,260) sọ tẹ́lẹ̀, wọ́n á sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀.”* 4 Àwọn yìí ni igi ólífì méjì+ àti ọ̀pá fìtílà méjì ṣàpẹẹrẹ,+ wọ́n dúró síwájú Olúwa ilẹ̀ ayé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́