Ẹ́sírà 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn àgbààgbà Júù ń bá iṣẹ́ ìkọ́lé náà lọ, wọ́n ń tẹ̀ síwájú,+ àsọtẹ́lẹ̀ wòlíì Hágáì+ àti Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò sì ń fún wọn níṣìírí; wọ́n parí iṣẹ́ ìkọ́lé náà nípa àṣẹ Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti nípa àṣẹ Kírúsì+ àti Dáríúsì+ àti Atasásítà+ ọba Páṣíà. Sekaráyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní oṣù kẹjọ, ọdún kejì ìjọba Dáríúsì,+ Jèhófà sọ fún wòlíì Sekaráyà*+ ọmọ Berekáyà ọmọ Ídò pé:
14 Àwọn àgbààgbà Júù ń bá iṣẹ́ ìkọ́lé náà lọ, wọ́n ń tẹ̀ síwájú,+ àsọtẹ́lẹ̀ wòlíì Hágáì+ àti Sekaráyà+ ọmọ ọmọ Ídò sì ń fún wọn níṣìírí; wọ́n parí iṣẹ́ ìkọ́lé náà nípa àṣẹ Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti nípa àṣẹ Kírúsì+ àti Dáríúsì+ àti Atasásítà+ ọba Páṣíà.