Sáàmù 103:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí bàbá ṣe ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+