ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 78:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àmọ́, ó jẹ́ aláàánú;+

      Ó máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n,* kò sì ní pa wọ́n run.+

      Ó máa ń fawọ́ ìbínú rẹ̀ sẹ́yìn lọ́pọ̀ ìgbà,+

      Kàkà tí ì bá fi jẹ́ kí gbogbo ìbínú rẹ̀ ru.

  • Àìsáyà 49:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ṣé obìnrin lè gbàgbé ọmọ rẹ̀ tó ṣì ń mu ọmú

      Tàbí kó má ṣàánú ọmọ tó lóyún rẹ̀?

      Tí àwọn obìnrin yìí bá tiẹ̀ gbàgbé, mi ò jẹ́ gbàgbé rẹ láé.+

  • Málákì 3:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé: “Wọn yóò di tèmi+ ní ọjọ́ tí mo bá sọ wọ́n di ohun ìní mi pàtàkì.*+ Èmi yóò ṣàánú wọn, bí èèyàn ṣe máa ń ṣàánú ọmọ rẹ̀ tó ń gbọ́ràn sí i lẹ́nu.+

  • Jémíìsì 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àdúrà ìgbàgbọ́ sì máa mú aláìsàn náà* lára dá, Jèhófà* máa gbé e dìde. Tó bá sì ti dẹ́ṣẹ̀, a máa dárí jì í.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́