Ìṣe 2:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Pétérù sọ fún wọn pé: “Ẹ ronú pìwà dà,+ kí a sì batisí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín+ ní orúkọ Jésù Kristi, kí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín lè ní ìdáríjì,+ ẹ ó sì gba ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́. Ìṣe 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ nígbà tí wọ́n gba Fílípì gbọ́, ẹni tó ń kéde ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run+ àti orúkọ Jésù Kristi, tọkùnrin tobìnrin wọn sì ń ṣèrìbọmi.+
38 Pétérù sọ fún wọn pé: “Ẹ ronú pìwà dà,+ kí a sì batisí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín+ ní orúkọ Jésù Kristi, kí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín lè ní ìdáríjì,+ ẹ ó sì gba ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́.
12 Àmọ́ nígbà tí wọ́n gba Fílípì gbọ́, ẹni tó ń kéde ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run+ àti orúkọ Jésù Kristi, tọkùnrin tobìnrin wọn sì ń ṣèrìbọmi.+