Mátíù 26:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó mú ife kan, ó dúpẹ́, ó sì gbé e fún wọn, ó ní: “Gbogbo yín, ẹ mu nínú rẹ̀,+ 28 torí èyí túmọ̀ sí ‘ẹ̀jẹ̀+ májẹ̀mú’ mi,+ tí a máa dà jáde nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn,+ kí wọ́n lè rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀.+ Éfésù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ipasẹ̀ ìràpadà tó fi ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ̀ san ni a fi rí ìtúsílẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni, ìdáríjì àwọn àṣemáṣe wa,+ nítorí ọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.
27 Ó mú ife kan, ó dúpẹ́, ó sì gbé e fún wọn, ó ní: “Gbogbo yín, ẹ mu nínú rẹ̀,+ 28 torí èyí túmọ̀ sí ‘ẹ̀jẹ̀+ májẹ̀mú’ mi,+ tí a máa dà jáde nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn,+ kí wọ́n lè rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀.+
7 Ipasẹ̀ ìràpadà tó fi ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ̀ san ni a fi rí ìtúsílẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni, ìdáríjì àwọn àṣemáṣe wa,+ nítorí ọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.