ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 20:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 bí mi ò ṣe fà sẹ́yìn nínú sísọ èyíkéyìí lára àwọn ohun tó lérè fún yín* tàbí nínú kíkọ́ yín ní gbangba+ àti láti ilé dé ilé.+

  • 1 Kọ́ríńtì 11:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nítorí ọwọ́ Olúwa ni mo ti gba èyí tí mo fi lé yín lọ́wọ́, pé Jésù Olúwa mú búrẹ́dì ní alẹ́ ọjọ́+ tí a ó dalẹ̀ rẹ̀,

  • 2 Pétérù 3:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, lẹ́tà kejì tí màá kọ sí yín nìyí, bíi ti àkọ́kọ́, mò ń rán yín létí kí n lè ta yín jí láti ronú jinlẹ̀,+ 2 kí ẹ máa rántí àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn wòlíì mímọ́ ti sọ ṣáájú* àti àṣẹ Olúwa àti Olùgbàlà nípasẹ̀ àwọn àpọ́sítélì yín.

  • 1 Jòhánù 3:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Lóòótọ́, àṣẹ tó pa nìyí pé: ká ní ìgbàgbọ́ nínú orúkọ Ọmọ rẹ̀ Jésù Kristi,+ ká sì nífẹ̀ẹ́ ara wa+ bó ṣe pàṣẹ fún wa gẹ́lẹ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́