Máàkù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Bó ṣe ń kọjá lọ, ó tajú kán rí Léfì ọmọ Áfíọ́sì tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.” Ló bá dìde, ó sì tẹ̀ lé e.+ Lúùkù 5:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Lẹ́yìn náà, ó jáde lọ, ó sì rí agbowó orí kan tó ń jẹ́ Léfì, tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.”+
14 Bó ṣe ń kọjá lọ, ó tajú kán rí Léfì ọmọ Áfíọ́sì tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.” Ló bá dìde, ó sì tẹ̀ lé e.+
27 Lẹ́yìn náà, ó jáde lọ, ó sì rí agbowó orí kan tó ń jẹ́ Léfì, tó jókòó sí ọ́fíìsì àwọn agbowó orí, ó sì sọ fún un pé: “Máa tẹ̀ lé mi.”+