Ìṣe 5:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ni wọ́n bá gba ìmọ̀ràn rẹ̀, wọ́n sì pe àwọn àpọ́sítélì, wọ́n nà wọ́n lẹ́gba,*+ wọ́n sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù mọ́, wọ́n wá fi wọ́n sílẹ̀. 2 Kọ́ríńtì 11:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ìgbà márùn-ún ni àwọn Júù nà mí ní ẹgba mọ́kàndínlógójì (39),+
40 Ni wọ́n bá gba ìmọ̀ràn rẹ̀, wọ́n sì pe àwọn àpọ́sítélì, wọ́n nà wọ́n lẹ́gba,*+ wọ́n sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù mọ́, wọ́n wá fi wọ́n sílẹ̀.