Mátíù 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ máa ṣọ́ra yín lọ́dọ̀ àwọn èèyàn; torí wọ́n máa fà yín lé àwọn ilé ẹjọ́ àdúgbò lọ́wọ́,+ wọ́n á sì nà yín+ nínú àwọn sínágọ́gù wọn.+ Máàkù 13:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Ní tiyín, ẹ máa ṣọ́ra yín. Àwọn èèyàn máa fà yín lé àwọn ilé ẹjọ́ àdúgbò lọ́wọ́,+ wọ́n máa lù yín nínú àwọn sínágọ́gù,+ ẹ sì máa dúró níwájú àwọn gómìnà àti àwọn ọba nítorí mi, kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.+
17 Ẹ máa ṣọ́ra yín lọ́dọ̀ àwọn èèyàn; torí wọ́n máa fà yín lé àwọn ilé ẹjọ́ àdúgbò lọ́wọ́,+ wọ́n á sì nà yín+ nínú àwọn sínágọ́gù wọn.+
9 “Ní tiyín, ẹ máa ṣọ́ra yín. Àwọn èèyàn máa fà yín lé àwọn ilé ẹjọ́ àdúgbò lọ́wọ́,+ wọ́n máa lù yín nínú àwọn sínágọ́gù,+ ẹ sì máa dúró níwájú àwọn gómìnà àti àwọn ọba nítorí mi, kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.+