-
Ìṣe 4:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ni Pétérù, tí ó ti kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ bá sọ fún wọn pé:
“Ẹ̀yin alákòóso àti ẹ̀yin àgbààgbà,
-
-
Ìṣe 25:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí náà, lọ́jọ́ kejì, Ágírípà àti Bẹ̀níìsì dé pẹ̀lú ọ̀pọ̀ afẹfẹyẹ̀yẹ̀, wọ́n sì wọnú gbọ̀ngàn àwùjọ pẹ̀lú àwọn ọ̀gágun àti àwọn ọkùnrin jàǹkàn-jàǹkàn ní ìlú náà; nígbà tí Fẹ́sítọ́ọ̀sì pàṣẹ, wọ́n mú Pọ́ọ̀lù wọlé.
-
-
Ìṣe 26:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àmọ́ Pọ́ọ̀lù sọ pé: “Kì í ṣe pé orí mi ń dà rú, Fẹ́sítọ́ọ̀sì Ọlọ́lá Jù Lọ, òótọ́ ọ̀rọ̀ tó mọ́gbọ́n dání ni mò ń sọ.
-