Ìṣe 5:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n gbá àwọn àpọ́sítélì mú,* wọ́n sì tì wọ́n mọ́ inú ẹ̀wọ̀n ìlú.+ 19 Àmọ́ ní òru, áńgẹ́lì Jèhófà* ṣí àwọn ilẹ̀kùn ẹ̀wọ̀n náà,+ ó mú wọn jáde, ó sì sọ pé: Hébérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+ Hébérù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?
18 Wọ́n gbá àwọn àpọ́sítélì mú,* wọ́n sì tì wọ́n mọ́ inú ẹ̀wọ̀n ìlú.+ 19 Àmọ́ ní òru, áńgẹ́lì Jèhófà* ṣí àwọn ilẹ̀kùn ẹ̀wọ̀n náà,+ ó mú wọn jáde, ó sì sọ pé:
7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+
14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?