ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 34:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Áńgẹ́lì Jèhófà pàgọ́ yí àwọn tó bẹ̀rù Rẹ̀ ká,+

      Ó sì ń gbà wọ́n sílẹ̀.+

  • Ìṣe 12:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́ wò ó! Áńgẹ́lì Jèhófà* dúró síbẹ̀,+ ìmọ́lẹ̀ kan sì tàn nínú yàrá ẹ̀wọ̀n náà. Ó gbá Pétérù pẹ́pẹ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́, ó jí i, ó sọ pé: “Dìde kíákíá!” Àwọn ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ náà sì bọ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.+

  • Ìṣe 16:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Lójijì, ìmìtìtì ilẹ̀ ńlá ṣẹlẹ̀, débi pé àwọn ìpìlẹ̀ ẹ̀wọ̀n mì tìtì. Yàtọ̀ síyẹn, gbogbo ilẹ̀kùn ṣí sílẹ̀ lójú ẹsẹ̀, ìdè gbogbo àwọn tí wọ́n dè sì tú.+

  • Hébérù 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+

  • Hébérù 1:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́