Mátíù 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà tí àwọn Farisí gbọ́ èyí, wọ́n sọ pé: “Ọ̀gbẹ́ni yìí kò lè lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, tí kò bá ní agbára Béélísébúbù,* alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù.”+ Máàkù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bákan náà, àwọn akọ̀wé òfin, tí wọ́n wá láti Jerúsálẹ́mù ń sọ pé: “Ó ní Béélísébúbù,* agbára alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù ló sì fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”+ Lúùkù 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ àwọn kan nínú wọn sọ pé: “Agbára Béélísébúbù,* alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù, ló fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”+ Jòhánù 8:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Àwọn Júù dá a lóhùn pé: “Ṣebí a ti sọ pé, ‘Ará Samáríà ni ọ́,+ ẹlẹ́mìí èṣù sì ni ọ́’?”+
24 Nígbà tí àwọn Farisí gbọ́ èyí, wọ́n sọ pé: “Ọ̀gbẹ́ni yìí kò lè lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, tí kò bá ní agbára Béélísébúbù,* alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù.”+
22 Bákan náà, àwọn akọ̀wé òfin, tí wọ́n wá láti Jerúsálẹ́mù ń sọ pé: “Ó ní Béélísébúbù,* agbára alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù ló sì fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”+
15 Àmọ́ àwọn kan nínú wọn sọ pé: “Agbára Béélísébúbù,* alákòóso àwọn ẹ̀mí èṣù, ló fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”+