Lúùkù 12:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹyọ owó méjì tí kò fi bẹ́ẹ̀ níye lórí* ni wọ́n ń ta ológoṣẹ́ márùn-ún, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? Síbẹ̀, Ọlọ́run ò gbàgbé* ìkankan nínú wọn.+ 7 Kódà, gbogbo irun orí yín la ti kà.+ Ẹ má bẹ̀rù; ẹ níye lórí gan-an ju ọ̀pọ̀ ológoṣẹ́ lọ.+
6 Ẹyọ owó méjì tí kò fi bẹ́ẹ̀ níye lórí* ni wọ́n ń ta ológoṣẹ́ márùn-ún, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? Síbẹ̀, Ọlọ́run ò gbàgbé* ìkankan nínú wọn.+ 7 Kódà, gbogbo irun orí yín la ti kà.+ Ẹ má bẹ̀rù; ẹ níye lórí gan-an ju ọ̀pọ̀ ológoṣẹ́ lọ.+