Mátíù 10:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹyọ owó kan tí kò fi bẹ́ẹ̀ níye lórí* ni wọ́n ń ta ológoṣẹ́ méjì, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? Síbẹ̀, ìkankan nínú wọn ò lè já bọ́ lulẹ̀* láìjẹ́ pé Baba yín mọ̀.+
29 Ẹyọ owó kan tí kò fi bẹ́ẹ̀ níye lórí* ni wọ́n ń ta ológoṣẹ́ méjì, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? Síbẹ̀, ìkankan nínú wọn ò lè já bọ́ lulẹ̀* láìjẹ́ pé Baba yín mọ̀.+