ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 13:55
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+

  • Jòhánù 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lẹ́yìn náà, òun, ìyá rẹ̀, àwọn arákùnrin rẹ̀+ àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí Kápánáúmù,+ àmọ́ wọn ò pẹ́ níbẹ̀.

  • Ìṣe 1:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Gbogbo wọn tẹra mọ́ àdúrà pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, àwọn àti àwọn obìnrin kan+ pẹ̀lú Màríà ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀.+

  • 1 Kọ́ríńtì 9:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 A ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tó jẹ́ onígbàgbọ́*+ lẹ́yìn bíi ti àwọn àpọ́sítélì yòókù àti àwọn arákùnrin Olúwa + àti Kéfà,*+ àbí a kò ní?

  • Gálátíà 1:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ mi ò rí ìkankan nínú àwọn àpọ́sítélì yòókù, àfi Jémíìsì+ àbúrò Olúwa.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́