-
Àìsáyà 6:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ó fèsì pé: “Lọ, kí o sì sọ fún àwọn èèyàn yìí pé:
-
-
Máàkù 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 kó lè jẹ́ pé, bí wọ́n tiẹ̀ ń wò, wọ́n lè máa wò, síbẹ̀ kí wọ́n má ṣe rí àti pé bí wọ́n tiẹ̀ ń gbọ́, wọ́n lè gbọ́, síbẹ̀ kó má sì yé wọn; wọn ò sì ní yí pa dà láé, kí wọ́n sì rí ìdáríjì.”+
-
-
Ìṣe 28:26, 27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 pé, ‘Lọ sọ fún àwọn èèyàn yìí pé: “Ó dájú pé ẹ ó gbọ́, àmọ́ kò ní yé yín rárá; ó dájú pé ẹ ó wò, àmọ́ ẹ ò ní rí nǹkan kan.+ 27 Nítorí ọkàn àwọn èèyàn yìí ti yigbì, wọ́n ti fi etí wọn gbọ́ àmọ́ wọn ò dáhùn, wọ́n ti di ojú wọn, kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran láé, kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́, kó má sì yé wọn nínú ọkàn wọn, kí wọ́n lè yí pa dà, kí n sì mú wọn lára dá.”’+
-