Máàkù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Afúnrúgbìn fún irúgbìn ọ̀rọ̀ náà.+ Lúùkù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìtumọ̀ àpèjúwe náà nìyí: Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni irúgbìn náà.+