Lúùkù 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Láàárín àkókò yìí, nígbà tí ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn kóra jọ débi pé wọ́n ń tẹ ara wọn mọ́lẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀, ó kọ́kọ́ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Ẹ ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí, ìyẹn àgàbàgebè.+
12 Láàárín àkókò yìí, nígbà tí ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn kóra jọ débi pé wọ́n ń tẹ ara wọn mọ́lẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀, ó kọ́kọ́ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Ẹ ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí, ìyẹn àgàbàgebè.+