Mátíù 21:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Ẹ gbọ́ àpèjúwe míì: Ọkùnrin kan wà, ó ní ilẹ̀, ó gbin àjàrà, ó sì ṣe ọgbà yí i ká,+ ó gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀, ó sì kọ́ ilé gogoro kan;+ ó wá gbé e fún àwọn tó ń dáko, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀ òkèèrè.+
33 “Ẹ gbọ́ àpèjúwe míì: Ọkùnrin kan wà, ó ní ilẹ̀, ó gbin àjàrà, ó sì ṣe ọgbà yí i ká,+ ó gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀, ó sì kọ́ ilé gogoro kan;+ ó wá gbé e fún àwọn tó ń dáko, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀ òkèèrè.+