Àìsáyà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó gbẹ́ ibẹ̀, ó sì kó àwọn òkúta ibẹ̀ kúrò. Ó gbin àjàrà pupa tó dáa sínú rẹ̀,Ó kọ́ ilé gogoro sí àárín rẹ̀,Ó sì gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀.+ Ó wá ń retí pé kí àjàrà náà so,Àmọ́ èso àjàrà igbó nìkan ló mú jáde. +
2 Ó gbẹ́ ibẹ̀, ó sì kó àwọn òkúta ibẹ̀ kúrò. Ó gbin àjàrà pupa tó dáa sínú rẹ̀,Ó kọ́ ilé gogoro sí àárín rẹ̀,Ó sì gbẹ́ ibi tí wọ́n ti ń fún wáìnì sínú rẹ̀.+ Ó wá ń retí pé kí àjàrà náà so,Àmọ́ èso àjàrà igbó nìkan ló mú jáde. +